Àwọn Ọba Kinni 17:15 BM

15 Obinrin yìí bá lọ, ó ṣe bí Elija ti wí. Òun ati Elija ati gbogbo ará ilé rẹ̀ sì ń jẹ àjẹyó fún ọpọlọpọ ọjọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 17

Wo Àwọn Ọba Kinni 17:15 ni o tọ