5 Elija bá lọ, ó ṣe bí OLUWA ti wí, ó sì ń gbé ẹ̀bá odò Keriti, ní ìhà ìlà oòrùn odò Jọdani.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 17
Wo Àwọn Ọba Kinni 17:5 ni o tọ