Àwọn Ọba Kinni 18:18 BM

18 Elija dáhùn pé, “Èmi kọ́ ni mò ń yọ Israẹli lẹ́nu, ìwọ gan-an ni. Ìwọ ati ilé baba rẹ; nítorí ẹ ti kọ òfin OLUWA sílẹ̀, ẹ sì ń sin oriṣa Baali.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 18

Wo Àwọn Ọba Kinni 18:18 ni o tọ