Àwọn Ọba Kinni 18:38 BM

38 OLUWA bá sọ iná sílẹ̀, iná náà sì jó ẹbọ náà ati igi, ati òkúta. Ó jó gbogbo ilẹ̀ ibẹ̀, ó sì lá gbogbo omi tí ó wà ninu kòtò.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 18

Wo Àwọn Ọba Kinni 18:38 ni o tọ