Àwọn Ọba Kinni 18:6 BM

6 Wọ́n ṣe àdéhùn ibi tí olukuluku yóo lọ wò ní gbogbo ilẹ̀ náà, olukuluku sì gba ọ̀nà tirẹ̀ lọ. Ahabu ọba lọ sí apá kan, Ọbadaya sì lọ sí apá keji.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 18

Wo Àwọn Ọba Kinni 18:6 ni o tọ