13 Nígbà tí Elija gbọ́ ohùn náà, ó fi ẹ̀wù rẹ̀ bojú, ó jáde, ó sì dúró ní ẹnu ọ̀nà ihò àpáta náà. Ohùn kan bi í pé, “Elija, kí ni ò ń ṣe níhìn-ín?”
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 19
Wo Àwọn Ọba Kinni 19:13 ni o tọ