2 Jesebẹli bá rán oníṣẹ́ kan sí Elija pẹlu ìbúra pé, “Kí àwọn oriṣa pa mí, bí n kò bá pa ọ́ ní ìwòyí ọ̀la, bí o ti pa àwọn wolii Baali.”
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 19
Wo Àwọn Ọba Kinni 19:2 ni o tọ