Àwọn Ọba Kinni 2:24 BM

24 Ó ní, “Mo fi orúkọ OLUWA alààyè búra, ẹni tí ó gbé mi ka orí ìtẹ́ Dafidi baba mi tí ó fi ìdí mi múlẹ̀, tí ó mú ìlérí rẹ̀ ṣẹ, tí ó sì fi ìjọba náà fún èmi ati arọmọdọmọ mi, lónìí olónìí ni Adonija yóo kú.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 2

Wo Àwọn Ọba Kinni 2:24 ni o tọ