27 Solomoni bá yọ Abiatari kúrò ninu iṣẹ́ alufaa OLUWA tí ó ń ṣe, ó sì jẹ́ kí ọ̀rọ̀ tí OLUWA sọ ní Ṣilo ṣẹ, nípa Eli alufaa ati arọmọdọmọ rẹ̀.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 2
Wo Àwọn Ọba Kinni 2:27 ni o tọ