29 Nígbà tí Solomoni gbọ́ pé Joabu ti sá lọ sinu Àgọ́ OLUWA, ati pé ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ, Solomoni rán Bẹnaya kí ó lọ pa á.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 2
Wo Àwọn Ọba Kinni 2:29 ni o tọ