Àwọn Ọba Kinni 2:31 BM

31 Ọba dá a lóhùn pé, “Ṣe bí Joabu ti ní kí o ṣe. Pa á, kí o sì sin ín. Nígbà náà ni ọrùn èmi, ati arọmọdọmọ Dafidi yóo tó mọ́ kúrò ninu ohun tí Joabu ṣe nígbà tí ó pa àwọn aláìṣẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 2

Wo Àwọn Ọba Kinni 2:31 ni o tọ