Àwọn Ọba Kinni 20:21 BM

21 Ahabu ọba bá lọ sójú ogun, ó kó ọpọlọpọ ẹṣin ati kẹ̀kẹ́ ogun; ó ṣẹgun àwọn ọmọ ogun Siria, ó sì pa ọpọlọpọ ninu wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 20

Wo Àwọn Ọba Kinni 20:21 ni o tọ