Àwọn Ọba Kinni 20:26 BM

26 Ní ọdún tí ó tẹ̀lé e, ní ìbẹ̀rẹ̀ àkókò òjò, ó kó àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jọ, ó sì kó wọn lọ sí ìlú Afeki, láti gbógun ti àwọn ọmọ Israẹli.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 20

Wo Àwọn Ọba Kinni 20:26 ni o tọ