Àwọn Ọba Kinni 20:41 BM

41 Wolii náà sáré tu aṣọ tí ó fi wé ojú, lẹsẹkẹsẹ ọba sì mọ̀ pé ọ̀kan ninu àwọn wolii ni.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 20

Wo Àwọn Ọba Kinni 20:41 ni o tọ