Àwọn Ọba Kinni 20:9 BM

9 Ahabu bá ranṣẹ pada sí Benhadadi ọba pé, “Mo faramọ́ ohun tí ó kọ́kọ́ bèèrè fún, ṣugbọn n kò lè gba ti ẹẹkeji yìí.”Àwọn oníṣẹ́ náà pada lọ jíṣẹ́ fún Benhadadi ọba.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 20

Wo Àwọn Ọba Kinni 20:9 ni o tọ