Àwọn Ọba Kinni 22:25 BM

25 Mikaaya bá dá a lóhùn pé, “O óo rí i nígbà tí ó bá di ọjọ́ náà, tí o bá sá wọ yàrá inú patapata lọ, láti fi ara pamọ́.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 22

Wo Àwọn Ọba Kinni 22:25 ni o tọ