32 Nítorí náà, nígbà tí wọ́n rí Jehoṣafati ọba, wọ́n ní, “Dájúdájú ọba Israẹli nìyí.” Wọ́n bá yipada láti bá a jà; ṣugbọn Jehoṣafati kígbe.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 22
Wo Àwọn Ọba Kinni 22:32 ni o tọ