49 Ahasaya ọba Israẹli, ọmọ Ahabu, ọba Israẹli sọ fún Jehoṣafati pé kí àwọn eniyan òun bá àwọn eniyan rẹ̀ tu ọkọ̀ lọ, ṣugbọn Jehoṣafati kò gbà.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 22
Wo Àwọn Ọba Kinni 22:49 ni o tọ