51 Ní ọdún kẹtadinlogun tí Jehoṣafati, ọba Juda, gun orí oyè ni Ahasaya, ọmọ Ahabu, gun orí oyè ní ilẹ̀ Israẹli, ó sì jọba ní Samaria fún ọdún meji.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 22
Wo Àwọn Ọba Kinni 22:51 ni o tọ