18 Ọjọ́ kẹta tí mo bí ọmọ tèmi ni obinrin yìí náà bí ọmọkunrin kan. Àwa meji péré ni a wà ninu ilé, kò sí ẹnìkẹta pẹlu wa.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 3
Wo Àwọn Ọba Kinni 3:18 ni o tọ