Àwọn Ọba Kinni 3:20 BM

20 Ó bá dìde ní ọ̀gànjọ́ òru, ó wá jí ọmọ tèmi gbé ní ẹ̀gbẹ́ mi nígbà tí mo sùn lọ, ó tẹ́ ẹ sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀, ó sì tẹ́ òkú ọmọ tirẹ̀ sọ́dọ̀ mi.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 3

Wo Àwọn Ọba Kinni 3:20 ni o tọ