Àwọn Ọba Kinni 3:27 BM

27 Ọba dáhùn, ó ní, “Ẹ má pa ààyè ọmọ yìí rárá, ẹ gbé e fún obinrin àkọ́kọ́. Òun gan-an ni ìyá rẹ̀.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 3

Wo Àwọn Ọba Kinni 3:27 ni o tọ