Àwọn Ọba Kinni 3:4 BM

4 Ọba a máa lọ sí Gibeoni láti rúbọ, nítorí pé níbẹ̀ ni pẹpẹ tí ó lókìkí jùlọ nígbà náà wà. A máa fi ẹgbẹrun (1,000) ẹran rú ẹbọ sísun lórí pẹpẹ náà.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 3

Wo Àwọn Ọba Kinni 3:4 ni o tọ