Àwọn Ọba Kinni 4:19 BM

19 Geberi, ọmọ Uri, ni alákòóso agbègbè Gileadi, níbi tí Sihoni ọba àwọn ará Amori ati Ogu ọba Baṣani ti jọba tẹ́lẹ̀ rí.Lẹ́yìn àwọn alákòóso mejeejila wọnyi, alákòóso àgbà kan tún wà fún gbogbo ilẹ̀ Juda.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 4

Wo Àwọn Ọba Kinni 4:19 ni o tọ