Àwọn Ọba Kinni 4:25 BM

25 Ní gbogbo àkókò Solomoni, gbogbo àwọn ọmọ Juda ati àwọn ọmọ Israẹli wà ní alaafia láti ìlú Dani títí dé Beeriṣeba. Ìdílé kọ̀ọ̀kan ní ọgbà àjàrà ati àwọn igi ọ̀pọ̀tọ́ tirẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 4

Wo Àwọn Ọba Kinni 4:25 ni o tọ