6 Ahiṣari ni olùdarí gbogbo àwọn tí ń ṣiṣẹ́ ninu ààfin. Adoniramu ọmọ Abida ni olórí àwọn tí ń kó àwọn eniyan ṣiṣẹ́ tipátipá.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 4
Wo Àwọn Ọba Kinni 4:6 ni o tọ