Àwọn Ọba Kinni 5:18 BM

18 Àwọn òṣìṣẹ́ Solomoni ati ti Hiramu, ati àwọn ọkunrin mìíràn láti ìlú Gebali ni wọ́n gbẹ́ òkúta, tí wọ́n sì la igi fún kíkọ́ ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 5

Wo Àwọn Ọba Kinni 5:18 ni o tọ