Àwọn Ọba Kinni 5:5 BM

5 Nisinsinyii, mo ti ṣe ìpinnu láti kọ́ ilé fún OLUWA Ọlọrun mi, gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ̀ sí Dafidi, baba mi, pé ọmọ rẹ̀, tí yóo gun orí oyè lẹ́yìn rẹ̀, ni yóo kọ́ ilé ìsìn fún òun.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 5

Wo Àwọn Ọba Kinni 5:5 ni o tọ