Àwọn Ọba Kinni 5:7 BM

7 Inú ọba Hiramu dùn pupọ nígbà tí wọ́n jíṣẹ́ Solomoni fún un. Ó ní, “Ẹni ìyìn ni OLUWA lónìí, nítorí pé ó fún Dafidi ní ọlọ́gbọ́n ọmọ, láti jọba lórí orílẹ̀-èdè ńlá yìí.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 5

Wo Àwọn Ọba Kinni 5:7 ni o tọ