Àwọn Ọba Kinni 6:12 BM

12 “Ní ti ilé ìsìn tí ò ń kọ́ yìí, bí o bá pa gbogbo òfin mi mọ́, tí o sì tẹ̀lé ìlànà mi, n óo ṣe gbogbo ohun tí mo ṣèlérí fún Dafidi, baba rẹ, fún ọ.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 6

Wo Àwọn Ọba Kinni 6:12 ni o tọ