Àwọn Ọba Kinni 6:20 BM

20 Gígùn ibi mímọ́ ti inú yìí jẹ́ ogún igbọnwọ, ó fẹ̀ ní ogún igbọnwọ, gíga rẹ̀ náà sì jẹ́ ogún igbọnwọ. Ojúlówó wúrà ni wọ́n fi bo gbogbo ibi mímọ́ náà; wọ́n sì fi pákó igi kedari ṣe pẹpẹ kan sibẹ.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 6

Wo Àwọn Ọba Kinni 6:20 ni o tọ