3 Yàrá àbáwọlé ilé ìsìn náà gùn ní ogún igbọnwọ, gígùn rẹ̀ ṣe déédé pẹlu ìbú rẹ̀, ó sì jìn sí ìsàlẹ̀ ní igbọnwọ mẹ́wàá níwájú.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 6
Wo Àwọn Ọba Kinni 6:3 ni o tọ