32 wọ́n gbẹ́ igi ọ̀pẹ, ati òdòdó, ati kerubu sí ara àwọn ìlẹ̀kùn náà; wọ́n sì yọ́ wúrà bò wọ́n patapata: ati igi ọ̀pẹ, ati òdòdó, ati àwọn Kerubu náà.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 6
Wo Àwọn Ọba Kinni 6:32 ni o tọ