35 Wọ́n gbẹ́ igi ọ̀pẹ, ati òdòdó, ati àwọn kerubu sí ara àwọn ìlẹ̀kùn náà, wọ́n sì fi wúrà bo gbogbo wọn.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 6
Wo Àwọn Ọba Kinni 6:35 ni o tọ