12 Ìlè mẹta mẹta òkúta gbígbẹ́ tí a fi ìlé kan igi kedari là láàrin, ni wọ́n fi kọ́ àgbàlá ńlá náà yípo. Bẹ́ẹ̀ náà sì ni àgbàlá ti inú ilé OLUWA ati yàrá àbáwọlé.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 7
Wo Àwọn Ọba Kinni 7:12 ni o tọ