Àwọn Ọba Kinni 7:29 BM

29 lórí àwọn ìtẹ́dìí yìí ni ó ya àwòrán àwọn kinniun, mààlúù ati ti kerubu sí. Wọ́n ṣe àwọn ọnà róbótó róbótó kan báyìí sí òkè àwọn kinniun ati akọ mààlúù náà ati sí ìsàlẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 7

Wo Àwọn Ọba Kinni 7:29 ni o tọ