Àwọn Ọba Kinni 7:35 BM

35 A mọ ìgbátí yíká òkè àwọn ìtẹ́lẹ̀ náà, tí ó ga sókè ní ààbọ̀ igbọnwọ, ìgbátí yìí wà ní téńté orí àwọn ìtẹ́lẹ̀ náà. Àṣepọ̀ ni wọ́n ṣe òun ati ìtẹ́dìí rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 7

Wo Àwọn Ọba Kinni 7:35 ni o tọ