Àwọn Ọba Kinni 7:37 BM

37 Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe ṣe ìtẹ́lẹ̀ mẹ́wẹ̀ẹ̀wá, bákan náà ni ó da gbogbo wọn, bákan náà ni wọ́n tó, bákan náà ni wọn sì rí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 7

Wo Àwọn Ọba Kinni 7:37 ni o tọ