45 Bàbà dídán ni Huramu fi ṣe àwọn ìkòkò ati ọkọ́ ati àwokòtò ati gbogbo ohun èlò inú ilé OLUWA tí ó ṣe fún Solomoni ọba.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 7
Wo Àwọn Ọba Kinni 7:45 ni o tọ