Àwọn Ọba Kinni 8:27 BM

27 “Ṣugbọn, ǹjẹ́ ìwọ Ọlọrun lè gbé inú ayé yìí? Nítorí pé bí gbogbo ọ̀run ti tóbi tó, kò gbà ọ́; kí á má ṣẹ̀ṣẹ̀ sọ ti ilé ìsìn tí mo kọ́ fún ọ?

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 8

Wo Àwọn Ọba Kinni 8:27 ni o tọ