29 Kí ojú rẹ lè máa wà lára ilé ìsìn yìí tọ̀sán-tòru, níbi tí o sọ pé o óo yà sọ́tọ̀ fún orúkọ rẹ. Kí o lè gbọ́ adura tí iranṣẹ rẹ ń gbà sí ibí yìí.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 8
Wo Àwọn Ọba Kinni 8:29 ni o tọ