Àwọn Ọba Kinni 8:39 BM

39 gbọ́ adura wọn láti ibùgbé rẹ lọ́run, dáríjì wọ́n, dá wọn lóhùn, kí o sì san ẹ̀san fún olukuluku gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀, (nítorí ìwọ nìkan ni o mọ èrò ọkàn ọmọ eniyan);

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 8

Wo Àwọn Ọba Kinni 8:39 ni o tọ