Àwọn Ọba Kinni 8:50 BM

50 Dárí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n, ati gbogbo àìdára tí wọ́n ṣe, kí o sì jẹ́ kí àwọn tí wọ́n kó wọn lẹ́rú ṣàánú wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 8

Wo Àwọn Ọba Kinni 8:50 ni o tọ