6 Lẹ́yìn náà, àwọn alufaa gbé Àpótí Ẹ̀rí OLUWA wá sí ààyè rẹ̀ ninu ibi mímọ́ ti inú, ní Ibi-Mímọ́-Jùlọ, lábẹ́ ìyẹ́ àwọn kerubu.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 8
Wo Àwọn Ọba Kinni 8:6 ni o tọ