15 Pẹlu ipá ni Solomoni ọba fi kó àwọn eniyan ṣiṣẹ́, tí ó fi kọ́ ilé OLUWA ati ààfin rẹ̀, ó sì kọ́ Milo, ati odi Jerusalẹmu, ati ìlú Hasori, ìlú Megido ati ìlú Geseri.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 9
Wo Àwọn Ọba Kinni 9:15 ni o tọ