Àwọn Ọba Kinni 9:8 BM

8 Ilé yìí yóo di òkìtì àlàpà, yóo sì di ohun àwòyanu ati ẹ̀gàn fún gbogbo ẹni tí ó bá ń rékọjá lọ. Wọn óo máa bi ara wọn léèrè pé, ‘Kí ló dé tí OLUWA fi ṣe báyìí sí ilẹ̀ yìí ati ilé yìí?’

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 9

Wo Àwọn Ọba Kinni 9:8 ni o tọ