Joṣua 1:6 BM

6 Múra, kí o sì ṣe ọkàn gírí, nítorí ìwọ ni o óo jẹ́ kí àwọn eniyan wọnyi gba ilẹ̀ tí mo ti búra fún àwọn baba wọn, pé n óo fún wọn.

Ka pipe ipin Joṣua 1

Wo Joṣua 1:6 ni o tọ