Joṣua 10:31 BM

31 Joṣua ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli bá gbéra láti Libina lọ sí Lakiṣi. Wọ́n dó tì í, wọ́n sì bá a jagun.

Ka pipe ipin Joṣua 10

Wo Joṣua 10:31 ni o tọ