Joṣua 10:33 BM

33 Horamu ọba Geseri wá láti ran àwọn ará ìlú Lakiṣi lọ́wọ́, Joṣua gbógun tì í, ó sì pa òun ati gbogbo àwọn eniyan rẹ̀ láìku ẹyọ ẹnìkan ṣoṣo.

Ka pipe ipin Joṣua 10

Wo Joṣua 10:33 ni o tọ