Joṣua 10:35 BM

35 Wọ́n gba ìlú náà ní ọjọ́ náà, wọ́n sì fi idà pa gbogbo àwọn eniyan ibẹ̀ patapata gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ṣe sí àwọn ará Lakiṣi.

Ka pipe ipin Joṣua 10

Wo Joṣua 10:35 ni o tọ